ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 49:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 “Jósẹ́fù+ jẹ́ èéhù igi eléso, igi tó ń so lẹ́bàá ìsun omi, tí àwọn ẹ̀ka rẹ̀ nà sórí ògiri.

  • Jẹ́nẹ́sísì 49:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ó* wá láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run bàbá rẹ, yóò sì ràn ọ́ lọ́wọ́, ó wà pẹ̀lú Olódùmarè, yóò sì fi àwọn ìbùkún ọ̀run lókè bù kún ọ, pẹ̀lú àwọn ìbùkún ibú nísàlẹ̀,+ pẹ̀lú àwọn ìbùkún ọmú àti ilé ọmọ.

  • Ìṣe 7:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àwọn olórí ìdílé náà jowú Jósẹ́fù,+ wọ́n sì tà á sí Íjíbítì.+ Àmọ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀,+ 10 ó gbà á nínú gbogbo ìpọ́njú rẹ̀, ó ṣe ojúure sí i, ó sì fún un ní ọgbọ́n níwájú Fáráò ọba Íjíbítì. Ó yàn án láti ṣàkóso Íjíbítì àti gbogbo ilé rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́