-
Jẹ́nẹ́sísì 39:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ọ̀gá ọgbà ẹ̀wọ̀n náà wá fi Jósẹ́fù ṣe olórí gbogbo àwọn ẹlẹ́wọ̀n tó wà nínú ẹ̀wọ̀n, òun ló sì máa ń rí sí i pé wọ́n ṣe gbogbo iṣẹ́ tó wà níbẹ̀.+
-