-
Jẹ́nẹ́sísì 40:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àmọ́ kí o rántí mi tí nǹkan bá ti ṣẹnuure fún ọ. Jọ̀ọ́, fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi, kí o sì sọ̀rọ̀ mi fún Fáráò, kí n lè kúrò níbí.
-