-
Jẹ́nẹ́sísì 40:21, 22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Ó dá olórí agbọ́tí pa dà sí ipò tó wà tẹ́lẹ̀, ó sì ń gbé ife fún Fáráò. 22 Àmọ́, ó gbé olórí alásè kọ́, bí Jósẹ́fù ṣe túmọ̀ àlá wọn fún wọn.+
-