Dáníẹ́lì 2:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Àmọ́ Ọlọ́run kan wà ní ọ̀run, tó jẹ́ Ẹni tó ń ṣí àwọn àṣírí payá,+ ó sì ti jẹ́ kí Ọba Nebukadinésárì mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ ní apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́. Àlá rẹ nìyí, àwọn ìran tí o sì rí nígbà tí o dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ nìyí: Émọ́sì 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ kò ní ṣe ohunkóhunLáìjẹ́ pé ó ti fi àṣírí ọ̀rọ̀ náà* han àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó jẹ́ wòlíì.+
28 Àmọ́ Ọlọ́run kan wà ní ọ̀run, tó jẹ́ Ẹni tó ń ṣí àwọn àṣírí payá,+ ó sì ti jẹ́ kí Ọba Nebukadinésárì mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ ní apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́. Àlá rẹ nìyí, àwọn ìran tí o sì rí nígbà tí o dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ nìyí:
7 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ kò ní ṣe ohunkóhunLáìjẹ́ pé ó ti fi àṣírí ọ̀rọ̀ náà* han àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó jẹ́ wòlíì.+