- 
	                        
            
            Jẹ́nẹ́sísì 39:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Nígbà tó yá, ó fi gbogbo ohun tó ní sí ìkáwọ́ Jósẹ́fù, kò sì da ara rẹ̀ láàmú nípa ohunkóhun àfi oúnjẹ tó ń jẹ. Yàtọ̀ síyẹn, Jósẹ́fù taagun, ó sì rẹwà. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 105:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        21 Ó fi í ṣe ọ̀gá lórí agbo ilé rẹ̀ Àti alákòóso lórí gbogbo ohun ìní rẹ̀,+ 
 
-