Jẹ́nẹ́sísì 47:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wọ́n sọ fún Fáráò pé: “A wá gbé ilẹ̀+ yìí bí àjèjì torí kò sí ibi tí agbo ẹran àwa ìránṣẹ́ rẹ yóò ti máa jẹko, torí ìyàn náà mú gidigidi ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Torí náà, jọ̀ọ́, jẹ́ kí àwa ìránṣẹ́ rẹ máa gbé ilẹ̀ Góṣénì.”+
4 Wọ́n sọ fún Fáráò pé: “A wá gbé ilẹ̀+ yìí bí àjèjì torí kò sí ibi tí agbo ẹran àwa ìránṣẹ́ rẹ yóò ti máa jẹko, torí ìyàn náà mú gidigidi ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Torí náà, jọ̀ọ́, jẹ́ kí àwa ìránṣẹ́ rẹ máa gbé ilẹ̀ Góṣénì.”+