ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 41:48, 49
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Ó sì ń kó gbogbo oúnjẹ jọ ní ilẹ̀ Íjíbítì fún ọdún méje náà, ó ń kó oúnjẹ pa mọ́ sí àwọn ìlú. Ó máa ń kó àwọn irè oko agbègbè ìlú kọ̀ọ̀kan pa mọ́ sí ìlú náà. 49 Jósẹ́fù sì ń kó ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ọkà pa mọ́, ó pọ̀ bí iyanrìn etíkun, débi pé wọn ò lè wọ̀n ọ́n torí kò ṣeé wọ̀n mọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́