Jẹ́nẹ́sísì 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́, o ò gbọ́dọ̀ jẹ èso igi ìmọ̀ rere àti búburú, torí ó dájú pé ọjọ́ tí o bá jẹ ẹ́ lo máa kú.”+ Jẹ́nẹ́sísì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Inú òógùn ojú rẹ ni wàá ti máa jẹun títí wàá fi pa dà sí ilẹ̀, torí inú rẹ̀ lo ti wá.+ Erùpẹ̀ ni ọ́, ìwọ yóò sì pa dà sí erùpẹ̀.”+ Róòmù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí ikú ni èrè* ẹ̀ṣẹ̀,+ àmọ́ ìyè àìnípẹ̀kun ni ẹ̀bùn tí Ọlọ́run ń fúnni+ nípasẹ̀ Kristi Jésù Olúwa wa.+ 1 Kọ́ríńtì 15:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí bí gbogbo èèyàn ṣe ń kú nínú Ádámù,+ bẹ́ẹ̀ ni a ó sọ gbogbo èèyàn di ààyè nínú Kristi.+
19 Inú òógùn ojú rẹ ni wàá ti máa jẹun títí wàá fi pa dà sí ilẹ̀, torí inú rẹ̀ lo ti wá.+ Erùpẹ̀ ni ọ́, ìwọ yóò sì pa dà sí erùpẹ̀.”+
23 Nítorí ikú ni èrè* ẹ̀ṣẹ̀,+ àmọ́ ìyè àìnípẹ̀kun ni ẹ̀bùn tí Ọlọ́run ń fúnni+ nípasẹ̀ Kristi Jésù Olúwa wa.+