Jẹ́nẹ́sísì 4:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Sẹ́ẹ̀tì náà bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ ọ́ ní Énọ́ṣì.+ Ìgbà yẹn ni àwọn èèyàn bẹ̀rẹ̀ sí í pe orúkọ Jèhófà. Lúùkù 3:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì, Lúùkù 3:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 ọmọ Énọ́ṣì,+ọmọ Sẹ́ẹ̀tì,+ọmọ Ádámù,+ọmọ Ọlọ́run.
26 Sẹ́ẹ̀tì náà bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ ọ́ ní Énọ́ṣì.+ Ìgbà yẹn ni àwọn èèyàn bẹ̀rẹ̀ sí í pe orúkọ Jèhófà.
23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì, Lúùkù 3:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 ọmọ Énọ́ṣì,+ọmọ Sẹ́ẹ̀tì,+ọmọ Ádámù,+ọmọ Ọlọ́run.