-
Jẹ́nẹ́sísì 45:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ṣe bẹ́ẹ̀, Jósẹ́fù fún wọn ní àwọn kẹ̀kẹ́ bí Fáráò ṣe pàṣẹ, ó tún fún wọn ní ohun tí wọ́n á jẹ lójú ọ̀nà.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 45:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àwọn ohun tó fi ránṣẹ́ sí bàbá rẹ̀ nìyí: kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ mẹ́wàá tó gbé àwọn nǹkan àmúṣọrọ̀ Íjíbítì àti abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ mẹ́wàá tó gbé ọkà àti búrẹ́dì àti ohun tí bàbá rẹ̀ máa jẹ lẹ́nu ìrìn àjò.
-