-
Jẹ́nẹ́sísì 37:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Wọ́n rí Jósẹ́fù tó ń bọ̀ ní ọ̀ọ́kán, àmọ́ kó tó dé ọ̀dọ̀ wọn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í gbìmọ̀ pọ̀ kí wọ́n lè pa á.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 50:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 ‘Ẹ sọ fún Jósẹ́fù pé: “Jọ̀ọ́, mo bẹ̀ ọ́, dárí àṣìṣe àwọn arákùnrin rẹ jì wọ́n, kí o sì gbójú fo ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n dá nígbà tí wọ́n ṣe ọ́ ní ibi.”’ Jọ̀ọ́, dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run bàbá rẹ jì wọ́n.” Nígbà tí Jósẹ́fù gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ó bú sẹ́kún.
-