Sáàmù 89:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Ta ló wà láàyè tí kò ní kú?+ Ṣé ó lè gba ara* rẹ̀ lọ́wọ́ agbára Isà Òkú ni?* (Sélà) Oníwàásù 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ohunkóhun tí ọwọ́ rẹ bá rí láti ṣe, fi gbogbo agbára rẹ ṣe é, nítorí pé kò sí iṣẹ́ tàbí èrò tàbí ìmọ̀ tàbí ọgbọ́n nínú Isà Òkú,*+ ibi tí ìwọ ń lọ. Hósíà 13:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá rà wọ́n pa dà lọ́wọ́ agbára Isà Òkú;*Màá gbà wọ́n pa dà lọ́wọ́ ikú.+ Ìwọ Ikú, oró rẹ dà?+ Ìwọ Isà Òkú, ìpanirun rẹ dà?+ Síbẹ̀, mi ò ní fojú àánú wò wọ́n.* Ìṣe 2:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 torí o ò ní fi mí* sílẹ̀ nínú Isà Òkú,* bẹ́ẹ̀ ni o ò ní jẹ́ kí ẹni ìdúróṣinṣin rẹ rí ìdíbàjẹ́.+ Ìfihàn 20:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Òkun yọ̀ǹda àwọn òkú tó wà nínú rẹ̀, ikú àti Isà Òkú* yọ̀ǹda àwọn òkú tó wà nínú wọn, a sì ṣèdájọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn bí iṣẹ́ ọwọ́ wọn ṣe rí.+
10 Ohunkóhun tí ọwọ́ rẹ bá rí láti ṣe, fi gbogbo agbára rẹ ṣe é, nítorí pé kò sí iṣẹ́ tàbí èrò tàbí ìmọ̀ tàbí ọgbọ́n nínú Isà Òkú,*+ ibi tí ìwọ ń lọ.
14 Màá rà wọ́n pa dà lọ́wọ́ agbára Isà Òkú;*Màá gbà wọ́n pa dà lọ́wọ́ ikú.+ Ìwọ Ikú, oró rẹ dà?+ Ìwọ Isà Òkú, ìpanirun rẹ dà?+ Síbẹ̀, mi ò ní fojú àánú wò wọ́n.*
13 Òkun yọ̀ǹda àwọn òkú tó wà nínú rẹ̀, ikú àti Isà Òkú* yọ̀ǹda àwọn òkú tó wà nínú wọn, a sì ṣèdájọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn bí iṣẹ́ ọwọ́ wọn ṣe rí.+