-
Jẹ́nẹ́sísì 43:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Nígbà tí Jósẹ́fù rí Bẹ́ńjámínì pẹ̀lú wọn, ojú ẹsẹ̀ ló sọ fún ọkùnrin tó ń bójú tó ilé rẹ̀ pé: “Mú àwọn ọkùnrin náà lọ sínú ilé, kí o pa ẹran, kí o sì se oúnjẹ, torí àwọn ọkùnrin náà yóò bá mi jẹun ní ọ̀sán.”
-