Jẹ́nẹ́sísì 43:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n fèsì pé: “Ọkùnrin náà bi wá nípa ara wa àti àwọn mọ̀lẹ́bí wa pé, ‘Ṣé bàbá yín ṣì wà láàyè? Ṣé ẹ ní arákùnrin míì?’ A sì sọ òótọ́ fún un.+ Báwo la ṣe fẹ́ mọ̀ pé yóò sọ pé, ‘Ẹ mú àbúrò yín wá’?”+
7 Wọ́n fèsì pé: “Ọkùnrin náà bi wá nípa ara wa àti àwọn mọ̀lẹ́bí wa pé, ‘Ṣé bàbá yín ṣì wà láàyè? Ṣé ẹ ní arákùnrin míì?’ A sì sọ òótọ́ fún un.+ Báwo la ṣe fẹ́ mọ̀ pé yóò sọ pé, ‘Ẹ mú àbúrò yín wá’?”+