Jẹ́nẹ́sísì 41:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Fáráò tún sọ fún Jósẹ́fù pé: “Èmi ni Fáráò, àmọ́ ẹnì kankan ò gbọ́dọ̀ ṣe ohunkóhun* ní gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì,+ láìjẹ́ pé o fọwọ́ sí i.” Jẹ́nẹ́sísì 45:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí náà, ẹ̀yin kọ́ lẹ rán mi wá síbí, Ọlọ́run tòótọ́ ni, torí kó lè fi mí ṣe olórí agbani-nímọ̀ràn* fún Fáráò, kó sì fi mí ṣe olúwa lórí gbogbo ilé rẹ̀ àti olórí gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì.+
44 Fáráò tún sọ fún Jósẹ́fù pé: “Èmi ni Fáráò, àmọ́ ẹnì kankan ò gbọ́dọ̀ ṣe ohunkóhun* ní gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì,+ láìjẹ́ pé o fọwọ́ sí i.”
8 Torí náà, ẹ̀yin kọ́ lẹ rán mi wá síbí, Ọlọ́run tòótọ́ ni, torí kó lè fi mí ṣe olórí agbani-nímọ̀ràn* fún Fáráò, kó sì fi mí ṣe olúwa lórí gbogbo ilé rẹ̀ àti olórí gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì.+