-
Jẹ́nẹ́sísì 43:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Torí náà, nígbà tí wọ́n jẹ ọkà tí wọ́n gbé wá láti Íjíbítì+ tán, bàbá wọn sọ fún wọn pé: “Ẹ pa dà lọ ra oúnjẹ díẹ̀ wá fún wa.”
-