-
Jẹ́nẹ́sísì 37:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ó sì yẹ̀ ẹ́ wò, ló bá kígbe pé: “Aṣọ ọmọ mi ni! Ẹranko burúkú ti pa á jẹ! Ó dájú pé ẹranko náà ti fa Jósẹ́fù ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ!”
-