Jẹ́nẹ́sísì 43:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mo fi dá ọ lójú pé kò sóhun tó máa ṣe ọmọ náà.*+ Ọwọ́ mi ni kí o ti béèrè rẹ̀. Tí mi ò bá mú un pa dà wá bá ọ, kí n sì fà á lé ọ lọ́wọ́, a jẹ́ pé mo ti ṣẹ̀ ọ́ títí láé nìyẹn.
9 Mo fi dá ọ lójú pé kò sóhun tó máa ṣe ọmọ náà.*+ Ọwọ́ mi ni kí o ti béèrè rẹ̀. Tí mi ò bá mú un pa dà wá bá ọ, kí n sì fà á lé ọ lọ́wọ́, a jẹ́ pé mo ti ṣẹ̀ ọ́ títí láé nìyẹn.