Jẹ́nẹ́sísì 37:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbà tí àwọn oníṣòwò tí wọ́n jẹ́ ọmọ Mídíánì+ ń kọjá lọ, wọ́n fa Jósẹ́fù jáde látinú kòtò omi náà, wọ́n sì tà á fún àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì ní ogún (20) ẹyọ fàdákà.+ Ni àwọn ọkùnrin yìí bá mú Jósẹ́fù lọ sí Íjíbítì. Ìṣe 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn olórí ìdílé náà jowú Jósẹ́fù,+ wọ́n sì tà á sí Íjíbítì.+ Àmọ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀,+
28 Nígbà tí àwọn oníṣòwò tí wọ́n jẹ́ ọmọ Mídíánì+ ń kọjá lọ, wọ́n fa Jósẹ́fù jáde látinú kòtò omi náà, wọ́n sì tà á fún àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì ní ogún (20) ẹyọ fàdákà.+ Ni àwọn ọkùnrin yìí bá mú Jósẹ́fù lọ sí Íjíbítì.