-
Jẹ́nẹ́sísì 47:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Jósẹ́fù sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ wò ó, mo ti ra ẹ̀yin àti ilẹ̀ yín fún Fáráò lónìí. Ẹ gba irúgbìn, kí ẹ sì gbìn ín sí ilẹ̀ náà.
-
-
Sáàmù 105:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó rán ọkùnrin kan lọ ṣáájú wọn,
Jósẹ́fù, ẹni tí wọ́n tà lẹ́rú.+
-