Jẹ́nẹ́sísì 45:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Wọ́n ròyìn fún un pé: “Jósẹ́fù ò tíì kú, ó ti di olórí gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì!”+ Àmọ́ ohun tí wọ́n sọ kò wọ Jékọ́bù lọ́kàn, torí kò gbà wọ́n gbọ́.+
26 Wọ́n ròyìn fún un pé: “Jósẹ́fù ò tíì kú, ó ti di olórí gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì!”+ Àmọ́ ohun tí wọ́n sọ kò wọ Jékọ́bù lọ́kàn, torí kò gbà wọ́n gbọ́.+