Jẹ́nẹ́sísì 46:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Jósẹ́fù múra kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ sílẹ̀, ó sì lọ pàdé Ísírẹ́lì bàbá rẹ̀ ní Góṣénì. Nígbà tó dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó dì mọ́ ọn* lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó sì sunkún fúngbà díẹ̀.*
29 Jósẹ́fù múra kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ sílẹ̀, ó sì lọ pàdé Ísírẹ́lì bàbá rẹ̀ ní Góṣénì. Nígbà tó dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó dì mọ́ ọn* lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó sì sunkún fúngbà díẹ̀.*