-
Jẹ́nẹ́sísì 45:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Nígbà tí wọ́n wá ń sọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Jósẹ́fù sọ fún wọn, tí Jékọ́bù sì wá rí àwọn kẹ̀kẹ́ tí Jósẹ́fù fi ránṣẹ́ pé kí wọ́n fi gbé e, ara Jékọ́bù bàbá wọn bẹ̀rẹ̀ sí í yá gágá.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 46:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Lẹ́yìn náà, Jékọ́bù kúrò ní Bíá-ṣébà, àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì sì fi kẹ̀kẹ́ tí Fáráò fi ránṣẹ́ gbé Jékọ́bù bàbá wọn àti àwọn ọmọ wọn àti àwọn ìyàwó wọn.
-