-
Nọ́ńbà 26:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àwọn ọmọ Síméónì+ nìyí ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Némúẹ́lì, ìdílé àwọn ọmọ Némúẹ́lì; látọ̀dọ̀ Jámínì, ìdílé àwọn ọmọ Jámínì; látọ̀dọ̀ Jákínì, ìdílé àwọn ọmọ Jákínì; 13 látọ̀dọ̀ Síírà, ìdílé àwọn ọmọ Síírà; látọ̀dọ̀ Ṣéọ́lù, ìdílé àwọn ọmọ Ṣéọ́lù.
-