-
Nọ́ńbà 26:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Àwọn ọmọ Sébúlúnì+ nìyí ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Sérédì, ìdílé àwọn ọmọ Sérédì; látọ̀dọ̀ Élónì, ìdílé àwọn ọmọ Élónì; látọ̀dọ̀ Jálíẹ́lì, ìdílé àwọn ọmọ Jálíẹ́lì.
-