1 Kíróníkà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bẹ́ńjámínì+ bí Bélà+ àkọ́bí rẹ̀, ọmọ rẹ̀ kejì ni Áṣíbélì,+ ìkẹta ni Áhárà, 1 Kíróníkà 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ọmọ Bélà ni Ádáárì, Gérà,+ Ábíhúdù,