-
Nọ́ńbà 26:38-40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì+ nìyí ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Bélà,+ ìdílé àwọn ọmọ Bélà; látọ̀dọ̀ Áṣíbélì, ìdílé àwọn ọmọ Áṣíbélì; látọ̀dọ̀ Áhírámù, ìdílé àwọn ọmọ Áhírámù; 39 látọ̀dọ̀ Ṣẹ́fúfámù, ìdílé àwọn ọmọ Súfámù; látọ̀dọ̀ Húfámù, ìdílé àwọn ọmọ Húfámù. 40 Àwọn ọmọ Bélà ni Áádì àti Náámánì:+ látọ̀dọ̀ Áádì, ìdílé àwọn ọmọ Áádì; látọ̀dọ̀ Náámánì, ìdílé àwọn ọmọ Náámánì.
-