-
Nọ́ńbà 26:48, 49Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Àwọn ọmọ Náfútálì+ nìyí ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Jáséélì, ìdílé àwọn ọmọ Jáséélì; látọ̀dọ̀ Gúnì, ìdílé àwọn ọmọ Gúnì; 49 látọ̀dọ̀ Jésérì, ìdílé àwọn ọmọ Jésérì; látọ̀dọ̀ Ṣílẹ́mù, ìdílé àwọn ọmọ Ṣílẹ́mù.
-