-
Jẹ́nẹ́sísì 41:30, 31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Àmọ́ lẹ́yìn ìyẹn, ó dájú pé ìyàn máa mú fún ọdún méje. Ó dájú pé gbogbo ohun tó pọ̀ rẹpẹtẹ nílẹ̀ Íjíbítì yóò di ohun ìgbàgbé, ìyàn yóò sì run ilẹ̀+ náà. 31 Wọn ò sì ní rántí ìgbà tí nǹkan pọ̀ rẹpẹtẹ ní ilẹ̀ náà torí ìyàn tó máa mú, torí pé ìyàn náà á mú gidigidi.
-