-
Jẹ́nẹ́sísì 41:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Kí Fáráò ṣe nǹkan kan lórí ọ̀rọ̀ yìí, kó yan àwọn alábòójútó ní ilẹ̀ náà, kó sì gba ìdá márùn-ún irè oko ilẹ̀ Íjíbítì ní ọdún méje tí ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ+ bá fi wà.
-