-
Jẹ́nẹ́sísì 47:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ilẹ̀ àwọn àlùfáà nìkan ni kò rà,+ torí Fáráò ló ń fún àwọn àlùfáà ní oúnjẹ. Oúnjẹ tí Fáráò ń fún wọn ni wọ́n gbára lé. Ìdí nìyẹn tí wọn ò fi ta ilẹ̀ wọn.
-