Jẹ́nẹ́sísì 50:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Níkẹyìn, Jósẹ́fù sọ fún àwọn arákùnrin rẹ̀ pé: “Mi ò ní pẹ́ kú, àmọ́ ó dájú pé Ọlọ́run ò ní gbàgbé yín,+ ó sì dájú pé yóò mú yín kúrò ní ilẹ̀ yìí lọ sí ilẹ̀ tó búra nípa rẹ̀ fún Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù.”+
24 Níkẹyìn, Jósẹ́fù sọ fún àwọn arákùnrin rẹ̀ pé: “Mi ò ní pẹ́ kú, àmọ́ ó dájú pé Ọlọ́run ò ní gbàgbé yín,+ ó sì dájú pé yóò mú yín kúrò ní ilẹ̀ yìí lọ sí ilẹ̀ tó búra nípa rẹ̀ fún Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù.”+