Ìfihàn 11:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́ inú bí àwọn orílẹ̀-èdè, ìwọ náà sì bínú, àkókò wá tó láti ṣèdájọ́ àwọn òkú àti láti san èrè+ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí wọ́n jẹ́ wòlíì+ àti àwọn ẹni mímọ́ àti àwọn tó ń bẹ̀rù orúkọ rẹ, ẹni kékeré àti ẹni ńlá àti láti run àwọn tó ń run ayé.”*+
18 Àmọ́ inú bí àwọn orílẹ̀-èdè, ìwọ náà sì bínú, àkókò wá tó láti ṣèdájọ́ àwọn òkú àti láti san èrè+ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí wọ́n jẹ́ wòlíì+ àti àwọn ẹni mímọ́ àti àwọn tó ń bẹ̀rù orúkọ rẹ, ẹni kékeré àti ẹni ńlá àti láti run àwọn tó ń run ayé.”*+