Jẹ́nẹ́sísì 29:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ó tún lóyún lẹ́ẹ̀kan sí i, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ pé: “Lọ́tẹ̀ yìí, màá yin Jèhófà.” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Júdà.*+ Lẹ́yìn ìyẹn, kò bímọ mọ́. Diutarónómì 33:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó sì súre fún Júdà+ pé: “Ìwọ Jèhófà, gbọ́ ohùn Júdà,+Kí o sì mú un pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀. Ọwọ́ rẹ̀ ti gbèjà* ohun tó jẹ́ tirẹ̀,Ràn án lọ́wọ́ kó lè borí àwọn ọ̀tá rẹ̀.”+
35 Ó tún lóyún lẹ́ẹ̀kan sí i, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ pé: “Lọ́tẹ̀ yìí, màá yin Jèhófà.” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Júdà.*+ Lẹ́yìn ìyẹn, kò bímọ mọ́.
7 Ó sì súre fún Júdà+ pé: “Ìwọ Jèhófà, gbọ́ ohùn Júdà,+Kí o sì mú un pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀. Ọwọ́ rẹ̀ ti gbèjà* ohun tó jẹ́ tirẹ̀,Ràn án lọ́wọ́ kó lè borí àwọn ọ̀tá rẹ̀.”+