ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 43:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Júdà wá rọ Ísírẹ́lì bàbá rẹ̀ pé: “Jẹ́ kí ọmọ náà bá mi lọ,+ sì jẹ́ ká máa lọ ká lè wà láàyè, ká má bàa kú,+ àwa àti ìwọ àti àwọn ọmọ+ wa. 9 Mo fi dá ọ lójú pé kò sóhun tó máa ṣe ọmọ náà.*+ Ọwọ́ mi ni kí o ti béèrè rẹ̀. Tí mi ò bá mú un pa dà wá bá ọ, kí n sì fà á lé ọ lọ́wọ́, a jẹ́ pé mo ti ṣẹ̀ ọ́ títí láé nìyẹn.

  • Jẹ́nẹ́sísì 46:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Jékọ́bù rán Júdà+ ṣáájú pé kó lọ sọ fún Jósẹ́fù pé òun ti wà lọ́nà Góṣénì. Nígbà tí wọ́n dé ilẹ̀ Góṣénì,+

  • 1 Kíróníkà 5:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Òótọ́ ni pé Júdà+ ta yọ àwọn arákùnrin rẹ̀, ọ̀dọ̀ rẹ̀ sì ni ẹni tó máa jẹ́ aṣáájú+ ti wá, síbẹ̀ Jósẹ́fù ló ni ẹ̀tọ́ àkọ́bí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́