Àwọn Onídàájọ́ 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà fèsì pé: “Júdà ni kó lọ.+ Wò ó! Màá fi* ilẹ̀ náà lé e lọ́wọ́.”