ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 24:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Màá rí i, àmọ́ kì í ṣe báyìí;

      Màá wò ó, àmọ́ kò tíì yá.

      Ìràwọ̀ kan+ máa ti ọ̀dọ̀ Jékọ́bù wá,

      Ọ̀pá àṣẹ+ kan sì máa dìde láti Ísírẹ́lì.+

      Ó sì dájú pé ó máa fọ́ iwájú orí Móábù*+ sí wẹ́wẹ́

      Àti agbárí gbogbo àwọn ọmọ ìdàrúdàpọ̀.

  • 2 Sámúẹ́lì 2:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ìgbà náà ni àwọn ọkùnrin Júdà wá, ibẹ̀ sì ni wọ́n ti fòróró yan Dáfídì ṣe ọba lórí ilé Júdà.+

      Wọ́n sọ fún Dáfídì pé: “Àwọn ará Jabeṣi-gílíádì ló sin Sọ́ọ̀lù.”

  • 2 Sámúẹ́lì 7:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ilé rẹ àti ìjọba rẹ máa fẹsẹ̀ múlẹ̀ títí láé níwájú rẹ; ìtẹ́ rẹ á sì fìdí múlẹ̀ títí láé.”’”+

      17 Nátánì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí àti gbogbo ìran tó rí+ fún Dáfídì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́