- 
	                        
            
            Àwọn Onídàájọ́ 15:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        15 Ó rí egungun tútù kan tó jẹ́ egungun páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́ akọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́; ó na ọwọ́ mú un, ó sì fi ṣá ẹgbẹ̀rún (1,000) ọkùnrin balẹ̀.+ 
 
-