Jóṣúà 17:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù sọ fún Jóṣúà pé: “Kí ló dé tí o fi kèké yan ilẹ̀ kan,+ tí o sì fún wa* ní ìpín kan ṣoṣo pé kó jẹ́ ogún wa? Èèyàn púpọ̀ ni wá, torí Jèhófà ti bù kún wa títí di báyìí.”+
14 Àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù sọ fún Jóṣúà pé: “Kí ló dé tí o fi kèké yan ilẹ̀ kan,+ tí o sì fún wa* ní ìpín kan ṣoṣo pé kó jẹ́ ogún wa? Èèyàn púpọ̀ ni wá, torí Jèhófà ti bù kún wa títí di báyìí.”+