-
Diutarónómì 33:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ó sọ nípa Bẹ́ńjámínì pé:+
“Kí ẹni ọ̀wọ́n Jèhófà máa gbé láìséwu lọ́dọ̀ rẹ̀;
Bó ṣe ń dáàbò bò ó ní gbogbo ọjọ́,
Á máa gbé láàárín èjìká rẹ̀.”
-