-
Àwọn Onídàájọ́ 20:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Lọ́jọ́ yẹn, àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì kó ẹgbẹ̀rún mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n (26,000) ọkùnrin tó ń lo idà jọ látinú àwọn ìlú wọn, yàtọ̀ sí ọgọ́rùn-ún méje (700) ọkùnrin tí wọ́n yàn láti Gíbíà. 16 Ọgọ́rùn-ún méje (700) ọkùnrin tí wọ́n yàn tí wọ́n jẹ́ ọlọ́wọ́ òsì wà lára àwọn ọmọ ogun yìí. Gbogbo àwọn ọkùnrin yìí ló lè fi kànnàkànnà ju òkúta ba ìbú fọ́nrán irun, tí kò sì ní tàsé.
-