-
Jẹ́nẹ́sísì 14:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kòtò tó ní ọ̀dà bítúmẹ́nì ló kún Àfonífojì* Sídímù. Nígbà tí àwọn ọba Sódómù àti Gòmórà fẹ́ sá lọ, wọ́n kó sínú àwọn kòtò náà, àwọn tó ṣẹ́ kù sì sá lọ sí agbègbè olókè.
-