-
Jẹ́nẹ́sísì 7:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Wọ́n wá wọlé, akọ àti abo nínú onírúurú ẹran, bí Ọlọ́run ṣe pàṣẹ fún un. Lẹ́yìn náà, Jèhófà ti ilẹ̀kùn pa.