Sáàmù 105:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó fi í ṣe ọ̀gá lórí agbo ilé rẹ̀Àti alákòóso lórí gbogbo ohun ìní rẹ̀,+ 22 Kó lè lo àṣẹ lórí* àwọn ìjòyè rẹ̀ bó ṣe fẹ́,*Kó sì kọ́ àwọn àgbààgbà rẹ̀ ní ọgbọ́n.+
21 Ó fi í ṣe ọ̀gá lórí agbo ilé rẹ̀Àti alákòóso lórí gbogbo ohun ìní rẹ̀,+ 22 Kó lè lo àṣẹ lórí* àwọn ìjòyè rẹ̀ bó ṣe fẹ́,*Kó sì kọ́ àwọn àgbààgbà rẹ̀ ní ọgbọ́n.+