Jóṣúà 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kèké+ wá mú ẹ̀yà Mánásè,+ torí òun ni àkọ́bí Jósẹ́fù.+ Torí pé ọkùnrin ogun ni Mákírù+ àkọ́bí Mánásè, tó sì jẹ́ bàbá Gílíádì, ó gba Gílíádì àti Báṣánì.+ 1 Kíróníkà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn ọmọ Mánásè+ ni: Ásíríélì, tí wáhàrì* rẹ̀ ará Síríà bí. (Ó bí Mákírù+ bàbá Gílíádì.
17 Kèké+ wá mú ẹ̀yà Mánásè,+ torí òun ni àkọ́bí Jósẹ́fù.+ Torí pé ọkùnrin ogun ni Mákírù+ àkọ́bí Mánásè, tó sì jẹ́ bàbá Gílíádì, ó gba Gílíádì àti Báṣánì.+