-
Jẹ́nẹ́sísì 2:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Kò sí igbó kankan ní ayé nígbà yẹn, ewéko kankan ò sì tíì hù, torí Jèhófà Ọlọ́run ò tíì rọ òjò sórí ilẹ̀, kò sì sí ẹnì kankan tó máa ro ilẹ̀.
-