Jẹ́nẹ́sísì 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ní ọjọ́ kìíní, oṣù kìíní, ọdún kọkànlélẹ́gbẹ̀ta (601),+ omi náà ti fà lórí ilẹ̀; Nóà ṣí ìbòrí áàkì náà, ó sì rí i pé ilẹ̀ ti ń gbẹ.
13 Ní ọjọ́ kìíní, oṣù kìíní, ọdún kọkànlélẹ́gbẹ̀ta (601),+ omi náà ti fà lórí ilẹ̀; Nóà ṣí ìbòrí áàkì náà, ó sì rí i pé ilẹ̀ ti ń gbẹ.