Lúùkù 17:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, àwọn ọkùnrin ń gbéyàwó, à ń fa àwọn obìnrin fún ọkọ, títí di ọjọ́ tí Nóà wọ ọkọ̀ áàkì,+ Ìkún Omi sì dé, ó pa gbogbo wọn run.+
27 wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, àwọn ọkùnrin ń gbéyàwó, à ń fa àwọn obìnrin fún ọkọ, títí di ọjọ́ tí Nóà wọ ọkọ̀ áàkì,+ Ìkún Omi sì dé, ó pa gbogbo wọn run.+