-
Jẹ́nẹ́sísì 7:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Omi náà fi ìgbọ̀nwọ́* mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (15) ga ju àwọn òkè lọ.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 8:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Omi náà wá bẹ̀rẹ̀ sí í fà lórí ilẹ̀. Lẹ́yìn àádọ́jọ (150) ọjọ́, omi náà ti lọ sílẹ̀.
-